الْحَمْدُ لِلَّهِ الَّذِي أَحْيَانَا بَعْدَ مَا أَمَاتَنَا وَإِلَيْهِ النُّشُورُ
Ìtumọ̀
Gbogbo ìyìn ni fún Allah, ẹni tí ó sọ wá di alààyè lẹ́yìn tí Ó ti pa wá (nínú oorun), ọ̀dọ̀ Rẹ̀ sì ni àjíǹde wà.
Pípè
Alhamdu lillahil-ladhi ahyana ba‘da ma amatana wa ilaihin-nuṣur.
Orísun: al-Bukhari, 6324
