يَهْدِيكُمُ اللَّهُ وَيُصْلِحُ بَالَكُمْ
Ìtumọ̀
Kí Allah tọ́ yín sọ́nà, kí Ó sì tún ipò yín ṣe!
Pípè
Yahdikumullahu wa yuslihu balakum!
Orísun: al-Bukhari, 6224
A máa ń kà wọ́n ní ìtẹ̀léra yìí
- Àdúà nígbà tí a bá sín
- Ìdáhùn fún ẹni tó sín
- Ìdáhùn ẹni tó sín
